Àwọn ọ̀dọ́ sọ ewu tó wà nínú kéèyàn máa fi nǹkan falẹ̀ àti àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa jára mọ́ ohun tó ní í ṣe.