Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Máa Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gba Ìbáwí

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Dáfídì ṣe ronú pìwà dà ẹ̀ṣẹ̀ tó dá pẹ̀lú Bátí-ṣébà àti ìdí tí Jèhófà fi dárí jì í. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ọlọ́run Dáhùn Àdúrà Nehemáyà

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Nehemáyà, kó o sì wo bí Ọlọ́run ṣe ràn án lọ́wọ́ kó lè kojú àwọn tó ń ta kò ó.

Bárúkù Fìgboyà Ṣe Ohun Tí Ó Tọ́

Ṣé o fẹ́ fìgboyà sọ ohun tó o gbà gbọ́ fún àwọn ẹlòmíì? Kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpẹẹrẹ Bárúkù.

Ọlọ́run Wo Hesekáyà Sàn

Ka ìtàn Bíbélì yìí kó o lè mọ bí o ṣe lè mú kí àdúrà tí ò ń gbà túbọ̀ nítumọ̀.