Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Ṣé Wàá Máa Ṣàánú?

Kẹ́kọ̀ọ́ látinú àkàwé tí Jésù ṣe nípa aláàánú ará Samáríà. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ọlọ́run Dáhùn Àdúrà Nehemáyà

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Nehemáyà, kó o sì wo bí Ọlọ́run ṣe ràn án lọ́wọ́ kó lè kojú àwọn tó ń ta kò ó.

Bárúkù Fìgboyà Ṣe Ohun Tí Ó Tọ́

Ṣé o fẹ́ fìgboyà sọ ohun tó o gbà gbọ́ fún àwọn ẹlòmíì? Kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpẹẹrẹ Bárúkù.

Máa Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gba Ìbáwí

Kí lo lè kọ́ lára Nátánì bó ṣe bá Dáfídì sọ̀rọ̀ nígbà tó fẹ́ tọ́ ọ sọ́nà?