Ibi tó o lè kọ èrò ẹ sí, kó o lè mọ bí wàá ṣe máa tọ́jú òbí ẹ tó bá ń ṣàìsàn, kó o sì tún tọ́jú ara rẹ.