Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́

ÌWÉ ÀJÁKỌ

Jẹ́ Kí Ohun Tó ò Gbàgbọ́ Dá Ọ Lójú: Kéèyàn Ma Tíì Ní Ìbálòpọ̀ Rí | Ìwé Àjákọ fún Àwọn Ọ̀dọ́

Ìwé àjákọ tó máa mú kí ìpinnu tó o ṣe láti tẹ̀ lé òfin Ọlọ́run nípa ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó túbọ̀ fẹsẹ̀ múlẹ̀.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Máa Ṣọ́wó Ná

Lo ìwé yìí láti fi mọ ìyàtọ̀ láàárin ohun tó o nílò àti ohun tó wù ẹ́, kó o sì fi wo bó ṣe bá ètò ìnáwó rẹ mu.

Bó O Ṣe Lè Kápá Ìmọ̀lára Rẹ Tí Kò Dáa

Ìwé yìí máa jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè kápá ìmọ̀lára rẹ tí kò dáa.

Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe

Ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti pinnu ẹni tó o lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀ tàbí irú ìwà tó o fẹ́ ní.