Ìwé àjákọ yìí máa jẹ́ kó o lè pinnu ohun tó wà nínú géèmù tó o fẹ́ gbá àti àkókò tí wàá lò nídìí rẹ̀.