Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àwọn Eré Ojú Pátákó

Àwọn eré bèbí ojú pátákó yìí sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tó ṣe pàtàkì, àmọ́ wọ́n tuni lára, wọ́n sì rọrùn lóye!

 

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Sọ Tinú Mi Fáwọn Òbí Mi?

Báwo lo ṣe lè sọ tinú ẹ fáwọn òbí ẹ tó bá tiẹ̀ ń ṣe ẹ́ bíi pé kó o máà bá ẹnì kankan sọ̀rọ̀?

Ṣé Fóònù tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ?

Ayé ti di ayé íńtánẹ́ẹ̀tì, àmọ́ kò yẹ kó di bárakú fún ẹ. Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí fóònù tàbí tablet bá ti di bárakú fún ẹ? Ká sọ pé ó ti di bárakú fún ẹ, kí lo lè ṣe sí i?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí N Lè Túbọ̀ Lómìnira?

O lè máa rò ó pé o kì í ṣe ọmọdé mọ́, àmọ́ àwọn òbí ẹ lè má gbà bẹ́ẹ̀. Kí lo lè máa ṣe kí wọ́n lè fọkàn tán ẹ?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó?

Tí wọ́n bá ti ń sọ̀rọ̀ ẹnìkan láì dáa, ṣe ni kó o tètè gbégbèésẹ̀!

Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán?

Mọ ìyàtọ̀ tó wà láàárín ìfẹ́ ojú lásán àti ìfẹ́ tòótọ́.

Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò

Máa ṣọ́ra fún ewu lórí ìkànnì tó o bá ń bá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ṣeré níbẹ̀.

Ta Ni Ore Tooto?

Ko soro rara lati ni ore buruku, amo bawo ni o se le ri ore tooto?

Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà

Kọ́ nípa ohun tó ń mú kí àwọn ọmọ kan máa halẹ̀ mọ́ àwọn ọmọ míì àti bí o ṣe lè borí wọn.