Bíbélì sọ ohun tó dáa jù tó yẹ ká ṣe nípa àwọn ìbéèrè tó díjú jù lọ láyé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sì ni àwọn ìmọ̀ràn rẹ̀ ti wúlò. Abala yìí máa jẹ́ kó o túbọ̀ rí bí Bíbélì ṣe wúlò tó.—2 Tímótì 3:16, 17.